YOR 시편 장 46

시편 46

YOR · 비교 · 오디오

1lọ́run ni ààbò àti agbára wa 2Nítorí náà àwa kì yóò bẹ̀rù, bí a tilẹ̀ ṣí ayé ní ìdí, 3Tí omi rẹ̀ tilẹ̀ ń hó tí ó sì ń mì Sela. 4Odò ńlá kan wà tí ṣíṣàn rẹ̀ mú inú ìlú Ọlọ́run dùn, 5Ọlọ́run wà pẹ̀lú rẹ̀, kò ní yẹ̀: 6Àwọn orílẹ̀-èdè ń bínú, àwọn ilẹ̀ ọba ṣubú, 7Olúwa àwọn ọmọ-ogun wà pẹ̀lú wa, 8Ẹ wá wo iṣẹ́ Olúwa 9O mú ọ̀tẹ̀ tán de òpin ilẹ̀ ayé 10Ẹ dúró jẹ́ẹ́, kí ẹ sì mọ̀ pé èmi ní Ọlọ́run. 11Olúwa àwọn ọmọ-ogun wà pẹ̀lú wa;

일일 한도 도달

플랜을 업그레이드하여 더 높은 일일 한도로 AI 기능을 계속 사용하세요.

모든 요금제 비교 →