YOR 시편 장 20

시편 20

YOR · 비교 · 오디오

1Kí Olúwa kí ó gbóhùn rẹ ní ọjọ́ ìpọ́njú; 2Kí ó rán ìrànlọ́wọ́ sí ọ, láti ibi mímọ́ 3Kí ó sì rántí gbogbo ẹbọ rẹ Sela. 4Kí ó fi fún ọ gẹ́gẹ́ bi ti èrò ọkàn rẹ 5Àwa yóò hó fún ayọ̀ nígbà tí o bá di aṣẹ́gun Olúwa kí ó mú gbogbo ìbéèrè rẹ̀ ṣẹ. 6Nísinsin yìí, èmi mọ̀ wí pé, Olúwa pa ẹni àmì òróró rẹ̀ mọ́. 7Àwọn mìíràn gbẹ́kẹ̀ wọn lé kẹ̀kẹ́, àwọn mìíràn gbẹ́kẹ̀ wọn lé ẹṣin, Olúwa Ọlọ́run wa. 8Wọ́n wólẹ̀, ní eékún, wọ́n sì ṣubú, 9Olúwa, fi ìṣẹ́gun fún ọba!

일일 한도 도달

플랜을 업그레이드하여 더 높은 일일 한도로 AI 기능을 계속 사용하세요.

모든 요금제 비교 →