YOR 시편 장 6

시편 6

YOR · 비교 · 오디오

1Olúwa, má ṣe bá mi wí nínú ìbínú rẹ 2Ṣàánú fún mi, Olúwa, nítorí èmi ń kú lọ; Olúwa, wò mí sán, nítorí egungun mi wà nínú ìnira. 3Ọkàn mi wà nínú ìrora. Olúwa, yóò ti pẹ́ tó? 4Yípadà, Olúwa, kí o sì gbà mí; 5Ẹnikẹ́ni kò ni rántí rẹ nígbà tí ó bá kú. 6Agara ìkérora mi dá mi tán. 7Ojú mi di aláìlera pẹ̀lú ìbànújẹ́; 8Kúrò lọ́dọ̀ mi, gbogbo ẹ̀yin tí ń ṣe iṣẹ́ ibi, Olúwa ti gbọ́ igbe mi. 9Olúwa ti gbọ́ ẹkún mi fún àánú; Olúwa ti gba àdúrà mi. 10Gbogbo àwọn ọ̀tá mi lójú yóò tì, wọn yóò sì dààmú;

일일 한도 도달

플랜을 업그레이드하여 더 높은 일일 한도로 AI 기능을 계속 사용하세요.

모든 요금제 비교 →