YOR 시편 장 62

시편 62

YOR · 비교 · 오디오

1Nínú Ọlọ́run nìkan ni ọkàn mi ti rí ìsinmi; 2Òun nìkan ní àpáta mi àti ìgbàlà mi; 3Ẹ̀yin ó ti máa kọ́lú ènìyàn kan pẹ́ tó? 4Kìkì èrò wọn ni láti bì ṣubú Sela. 5Nínú Ọlọ́run nìkan ni ìsinmi wà, ìwọ Ọlọ́run mi. 6Òun nìkan ní àpáta àti ìgbàlà mi; 7Ìgbàlà mi àti ògo mi dúró nínú Ọlọ́run; 8Gbẹ́kẹ̀lé ní gbogbo ìgbà, ẹ̀yin ènìyàn; 9Nítòótọ́, asán ni àwọn ọmọ ènìyàn, 10Má ṣe gbẹ́kẹ̀lé ìnilára, 11Ọlọ́run ti sọ̀rọ̀ lẹ́ẹ̀kejì, 12pẹ̀lúpẹ̀lú, Olúwa, tìrẹ ni àánú;

일일 한도 도달

플랜을 업그레이드하여 더 높은 일일 한도로 AI 기능을 계속 사용하세요.

모든 요금제 비교 →