YOR 시편 장 96

시편 96

YOR · 비교 · 오디오

1 kọrin tuntun sí Olúwa, Olúwa gbogbo ayé. 2Ẹ kọrin sí Olúwa, yin orúkọ rẹ̀ 3Ẹ sọ ti ògo rẹ̀ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè 4Nítorí títóbi ní Olúwa ẹni tí ìyìn tọ́ sí; 5Nítorí asán ni gbogbo àwọn òrìṣà orílẹ̀-èdè Olúwa dá àwọn ọ̀run. 6Ọlá àti ọláńlá wà ní iwájú rẹ̀ 7Ẹ fi fún Olúwa, ẹ̀yin ìbátan ènìyàn, Olúwa. 8Ẹ fi ògo tí ó tọ́ sí Olúwa fún un; 9Ẹ máa sin Olúwa nínú ẹwà ìwà mímọ́ rẹ̀; 10Sọ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè, “Olúwa jẹ ọba.” 11Jẹ́ kí àwọn ọ̀run kí ó yọ̀, kí ayé sì pariwo 12Jẹ́ kí oko kún fún ayọ̀, àti ohun gbogbo tí ń bẹ nínú rẹ̀; 13Wọn yóò kọrin níwájú Olúwa,

일일 한도 도달

플랜을 업그레이드하여 더 높은 일일 한도로 AI 기능을 계속 사용하세요.

모든 요금제 비교 →