YOR 이사야 장 63

이사야 63

YOR · 비교 · 오디오

1Ta nì eléyìí tí ó Edomu wá, 2Èéṣe tí aṣọ yín fi pupa 3“Èmi nìkan ti dá tẹ ìfúntí wáìnì; 4Nítorí ọjọ́ ẹ̀san wà ní ọkàn mi 5Mo wò, ṣùgbọ́n kò sí ẹnìkan láti ṣe ìrànwọ́. 6Mo tẹ orílẹ̀-èdè mọ́lẹ̀ nínú ìbínú mi; 7Èmi yóò sọ nípa àánú Olúwa, Olúwa ti ṣe fún wa, 8Ó wí pé, “Lóòtítọ́ ènìyàn mi ni wọ́n, 9Nínú gbogbo ìpọ́njú wọn, inú òun pẹ̀lú bàjẹ́ 10Síbẹ̀síbẹ̀ wọ́n ṣọ̀tẹ̀ 11Lẹ́yìn náà ni àwọn ènìyàn rẹ̀ rántí ọjọ́ ìgbà n nì, 12ta ni ó rán apá ògo ti agbára rẹ̀ 13ta ni ó síwájú wọn la àwọn ọ̀gbun nì já? 14gẹ́gẹ́ bí ọ̀wọ́ ẹran tí ó lọ sí pápá oko, Olúwa. 15Bojú wolẹ̀ láti ọ̀run kí o sì rí i 16Ṣùgbọ́n ìwọ ni baba wa, Olúwa ni Baba wa, 17Èéṣe Olúwa tí o fi jẹ́ kí a ṣáko kúrò ní ojú ọ̀nà rẹ 18Fún ìgbà díẹ̀ ni àwọn ènìyàn rẹ fi gba ibi mímọ́ rẹ, 19Àwa jẹ́ tìrẹ láti ìgbà n nì;

일일 한도 도달

플랜을 업그레이드하여 더 높은 일일 한도로 AI 기능을 계속 사용하세요.

모든 요금제 비교 →