YOR 이사야 장 46

이사야 46

YOR · 비교 · 오디오

1Beli tẹrí i rẹ̀ ba, Nebo bẹ̀rẹ̀ mọ́lẹ̀; 2Wọ́n bẹ̀rẹ̀ wọ́n sì foríbalẹ̀ papọ̀; 3“Tẹ́tí sí mi, ìwọ ilé Jakọbu, 4Pẹ̀lúpẹ̀lú sí àwọn arúgbó àti ewú orí yín, 5“Ta ni ìwọ yóò fi mí wé tàbí ta ni èmi yóò bá dọ́gba? 6Ọ̀pọ̀ da wúrà sílẹ̀ nínú àpò wọn 7Wọ́n gbé e lé èjìká wọn, wọ́n rù wọ́n, 8“Rántí èyí, fi í sí ọkàn rẹ, 9Rántí àwọn nǹkan àtẹ̀yìnwá, àwọn ti àtijọ́-tijọ́; 10Mo fi òpin hàn láti ìbẹ̀rẹ̀ wá, 11Láti ìlà-oòrùn wá ni mo ti pe ẹyẹ ajẹran wá; 12Gbọ́ tèmi, ẹ̀yin alágídí ọkàn, 13Èmi ń mú òdodo mi bọ̀ nítòsí,

일일 한도 도달

플랜을 업그레이드하여 더 높은 일일 한도로 AI 기능을 계속 사용하세요.

모든 요금제 비교 →