YOR 이사야 장 61

이사야 61

YOR · 비교 · 오디오

1̀mí Olúwa Olódùmarè wà lára mi Olúwa ti fi àmì òróró yàn mí 2láti kéde ọdún ojúrere Olúwa 3àti láti pèsè fún àwọn tí inú wọn bàjẹ́ ní Sioni Olúwa 4Wọn yóò tún àwọn ahoro àtijọ́ kọ́ 5Àwọn àjèjì ni yóò máa da ọ̀wọ́ ẹran rẹ; 6A ó sì máa pè yín ní àlùfáà Olúwa, 7Dípò àbùkù wọn 8“Nítorí Èmi, Olúwa fẹ́ràn ìdájọ́ òdodo; 9A ó mọ ìrandíran wọn láàrín àwọn orílẹ̀-èdè Olúwa ti bùkún.” 10Èmi yọ̀ gidigidi nínú Olúwa; 11Gẹ́gẹ́ bí ilẹ̀ ti í mú irúgbìn jáde Olúwa Olódùmarè yóò ṣe mú òdodo àti ìyìn

일일 한도 도달

플랜을 업그레이드하여 더 높은 일일 한도로 AI 기능을 계속 사용하세요.

모든 요금제 비교 →