YOR 이사야 장 52

이사야 52

YOR · 비교 · 오디오

1Jí, jí, ìwọ Sioni, 2Gbọn eruku rẹ kúrò; 3Nítorí èyí ni ohun tí Olúwa wí, 4Nítorí èyí ni ohun tí Olúwa Olódùmarè wí. 5“Àti ní àkókò yìí, kí ni mo ní níbí?” ni Olúwa wí. Olúwa wí. 6Nítorí náà àwọn ènìyàn mi yóò mọ orúkọ mi; 7Báwo ni ó ṣe dára tó lórí òkè 8Tẹ́tí sílẹ̀! Àwọn olùṣọ́ rẹ gbé ohùn wọn sókè Olúwa padà sí Sioni, 9Ẹ bú sí orin ayọ̀ papọ̀, Olúwa ti tu àwọn ènìyàn rẹ̀ nínú, 10Olúwa yóò ṣí apá mímọ́ rẹ̀ sílẹ̀ 11Ẹ túká, ẹ túká, ẹ jáde kúrò níhìn-ín yìí! Olúwa. 12Ṣùgbọ́n ẹ̀yin kì yóò yára kúrò Olúwa ni yóò síwájú yín lọ, 13Kíyèsi i, ìránṣẹ́ mi yóò hùwà ọlọ́gbọ́n; 14Gẹ́gẹ́ bí a ti rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ tí wọ́n ń bu ọlá fún un— 15Bẹ́ẹ̀ ni yóò ṣe bomirin àwọn orílẹ̀-èdè ká,

일일 한도 도달

플랜을 업그레이드하여 더 높은 일일 한도로 AI 기능을 계속 사용하세요.

모든 요금제 비교 →