YOR 이사야 장 43

이사야 43

YOR · 비교 · 오디오

1ùgbọ́n ní ìsinsin yìí, ohun tí Olúwa wí nìyìí, 2Nígbà tí ìwọ bá ń la omi kọjá, 3Nítorí Èmi ni Olúwa Ọlọ́run rẹ, 4Nítorí pé o ṣe iyebíye àti ọ̀wọ́n níwájú mi, 5Má bẹ̀rù nítorí èmi wà pẹ̀lú rẹ; 6Èmi yóò sọ fún àríwá pé, ‘Fi wọ́n sílẹ̀!’ 7ẹnikẹ́ni tí a ń pe orúkọ mi mọ́, 8Sin àwọn tí ó ní ojú ṣùgbọ́n tí wọ́n fọ́jú jáde, 9Gbogbo orílẹ̀-èdè kó ra wọn jọ 10“Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí mi,” ni Olúwa wí, 11Èmi, àní Èmi, Èmi ni Olúwa, 12Èmi ti fihàn, mo gbàlà mo sì ti kéde Olúwa wí, “Pé Èmi ni Ọlọ́run. 13Bẹ́ẹ̀ ni, àti láti ayérayé Èmi ni ẹni náà. 14Èyí ni ohun tí Olúwa wí, 15Èmi ni Olúwa, Ẹni Mímọ́ rẹ, 16Èyí ni ohun tí Olúwa wí, 17ẹni tí ó wọ́ àwọn kẹ̀kẹ́ àti ẹṣin jáde, 18“Gbàgbé àwọn ohun àtẹ̀yìnwá; 19Wò ó, Èmi ń ṣe ohun tuntun! 20Àwọn ẹhànnà ẹranko bọ̀wọ̀ fún mi, 21àwọn ènìyàn tí mo dá fún ara mi 22“Síbẹ̀síbẹ̀ ìwọ kò tí ì ké pè mí, ìwọ Jakọbu, 23Ìwọ kò tí ì mú àgùntàn wá fún mi fún ẹbọ sísun, 24Ìwọ kò tí ì ra kalamusi olóòórùn dídùn fún mi, 25“Èmi, àní Èmi, Èmi ni ẹni tí ó wẹ 26Bojú wo ẹ̀yìn rẹ fún mi, 27Baba yín àkọ́kọ́ dẹ́ṣẹ̀; 28Nítorí náà, èmi ti sọ àwọn olórí ibi mímọ́ náà di àìmọ́,

일일 한도 도달

플랜을 업그레이드하여 더 높은 일일 한도로 AI 기능을 계속 사용하세요.

모든 요금제 비교 →