YOR 이사야 장 1

이사야 1

YOR · 비교 · 오디오

1Ìran sí Juda àti Jerusalẹmu èyí tí Isaiah ọmọ Amosi rí ní àsìkò ìjọba Ussiah, Jotamu, Ahasi àti Hesekiah àwọn ọba Juda. 2Gbọ́ ẹ̀yin ọ̀run! Fi etí sílẹ̀, ìwọ ayé! Olúwa ti sọ̀rọ̀: 3Màlúù mọ olówó rẹ̀, 4Á à! Orílẹ̀-èdè ẹlẹ́ṣẹ̀, Olúwa sílẹ̀ 5Èéṣe tí a ó fi tún lù yín mọ́? 6Láti àtẹ́lẹsẹ̀ yín dé àtàrí yín 7Orílẹ̀-èdè yín dahoro, 8Ọmọbìnrin Sioni ni a fi sílẹ̀ 9Àyàfi bí Olúwa àwọn ọmọ-ogun 10Gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa, 11“Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹbọ yín Olúwa wí. 12Nígbà tí ẹ wá farahàn níwájú mi, 13Ẹ má mú ọrẹ asán wá mọ́! 14Ayẹyẹ oṣù tuntun yín àti àjọ̀dún tí a yàn, 15Nígbà tí ẹ bá tẹ́ ọwọ́ yín sókè ni àdúrà, 16“Wẹ̀ kí ẹ sì jẹ́ kí ara yín mọ́. 17kọ́ láti ṣe rere! 18“Ẹ wá ní ìsinsin yìí, ẹ jẹ́ kí a jọ ṣàṣàrò,” Olúwa wí. 19Tí ẹ̀yin bá fẹ́, tí ẹ sì gbọ́rọ̀, 20Ṣùgbọ́n tí ẹ bá kọ̀ tí ẹ sì ṣọ̀tẹ̀, Olúwa la ti sọ ọ́. 21Wo bí ìlú òtítọ́ ṣe di àgbèrè! 22Fàdákà rẹ ti di ìpẹ́pẹ́, 23Ọlọ̀tẹ̀ ni àwọn aláṣẹ yín, 24Nítorí náà ni Olúwa, Olúwa àwọn ọmọ-ogun, 25Èmi yóò pa ọwọ́ mi dà sí ọ, 26Èmi yóò mú àwọn adájọ́ rẹ bọ̀ sí ipò gẹ́gẹ́ bí i ti àtijọ́, 27A ó fi ìdájọ́ òtítọ́ ra Sioni padà, 28Ṣùgbọ́n àwọn ọlọ̀tẹ̀ àti àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ni a ó parun. Olúwa sílẹ̀ ni yóò ṣègbé. 29“Ojú yóò tì yín nítorí igi óákù mímọ́ 30Ẹ ó sì dàbí igi óákù tí ewé rẹ̀ ti rọ, 31Alágbára ọkùnrin náà yóò sì dàbí ohun ìdáná,

일일 한도 도달

플랜을 업그레이드하여 더 높은 일일 한도로 AI 기능을 계속 사용하세요.

모든 요금제 비교 →