YOR 시편 장 61

시편 61

YOR · 비교 · 오디오

1Gbọ́ ẹkún mi, Ọlọ́run; 2Láti òpin ayé wá ni èmi yóò pè ọ́, 3Nítorí ìwọ ti jẹ́ ibi ààbò mi, 4Mo ń lépa láti máa gbé nínú àgọ́ rẹ títí láé 5Nítorí ìwọ ti gbọ́ àwọn ẹ̀jẹ́ mi, Ọlọ́run; 6Jẹ́ kí ẹ̀mí ọba kí ó gùn, 7Kí ó máa jẹ ọba níwájú Ọlọ́run títí láé; 8Nígbà náà ni èmi ó máa kọrin ìyìn sí orúkọ rẹ títí láé

일일 한도 도달

플랜을 업그레이드하여 더 높은 일일 한도로 AI 기능을 계속 사용하세요.

모든 요금제 비교 →