YOR 시편 장 29

시편 29

YOR · 비교 · 오디오

1 fi fún Olúwa, ẹ̀yin ẹ̀dá ọ̀run, Olúwa, ògo àti alágbára. 2Fi fún Olúwa, àní ògo orúkọ rẹ̀; Olúwa nínú ẹwà ìwà mímọ́. 3Ohùn Olúwa n ré àwọn omi kọjá; Olúwa san ara. 4Ohùn Olúwa ní agbára; Olúwa kún fún ọláńlá. 5Ohùn Olúwa fa igi kedari; Olúwa náà ló fọ́ igi kedari Lebanoni ya. 6Ó mú Lebanoni fo bí i ọmọ màlúù, 7Ohùn Olúwa ń ya 8Ohùn Olúwa ń mi aginjù. Olúwa mi aginjù Kadeṣi. 9Ohùn Olúwa ní ó lọ igi óákù, ó n mú abo àgbọ̀nrín bí, 10Olúwa jókòó, Ó sì jẹ ọba lórí ìṣàn omi; Olúwa jókòó lórí ìtẹ́ gẹ́gẹ́ bí Ọba títí láéláé. 11Kí Olúwa fi agbára fún àwọn ènìyàn rẹ̀;

일일 한도 도달

플랜을 업그레이드하여 더 높은 일일 한도로 AI 기능을 계속 사용하세요.

모든 요금제 비교 →