YOR 시편 장 11

시편 11

YOR · 비교 · 오디오

1Ìgbẹ́kẹ̀lé mi wà nínú Olúwa. 2Wò ó nítorí náà, ènìyàn búburú fa ọfà rẹ̀; 3Nígbà tí ìpìlẹ̀ bá bàjẹ́ 4Olúwa ń bẹ nínú tẹmpili mímọ́ rẹ̀; Olúwa ń bẹ lórí ìtẹ́ rẹ̀ ní ọ̀run. 5Olúwa ń yẹ olódodo wò, 6Sí orí àwọn ènìyàn búburú ni yóò rọ̀jò 7Nítorí, olódodo ní Olúwa,

일일 한도 도달

플랜을 업그레이드하여 더 높은 일일 한도로 AI 기능을 계속 사용하세요.

모든 요금제 비교 →