YOR Psalm Chương 84

Psalm 84

YOR · So sánh · Âm thanh

1Ibùgbé rẹ̀ ti lẹ́wà tó, Olúwa àwọn ọmọ-ogun! 2Ọkàn mi ń ṣàfẹ́rí nítòótọ́ Olúwa 3Nítòótọ́ ológoṣẹ́ ri ilé, Olúwa àwọn ọmọ-ogun, ọba mí àti Ọlọ́run mi. 4Ìbùkún ní fún àwọn tí ó ń gbé inú ilé rẹ; 5Ìbùkún ni fún àwọn tí agbára wọn wà nínú rẹ 6Àwọn tí ń la àfonífojì omijé lọ 7Wọ́n ń lọ láti ipa dé ipá 8Gbọ́ àdúrà mi, Olúwa Ọlọ́run Alágbára; 9Wo asà wa, Ọlọ́run; 10Dídára ní ọjọ́ kan ní ààfin rẹ 11Nítorí Olúwa Ọlọ́run jẹ́ òòrùn àti asà; Olúwa fún ni ní ojúrere àti ọlá; 12Olúwa àwọn ọmọ-ogun,

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →