YOR Psalm Chương 146

Psalm 146

YOR · So sánh · Âm thanh

1 fi ìyìn fún Olúwa. Olúwa, ìwọ ọkàn mi. 2Èmi yóò yin Olúwa ní gbogbo ayé mi, 3Ẹ má ṣe ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú àwọn ọmọ-aládé, 4Ẹ̀mí rẹ jáde lọ, ó padà sí erùpẹ̀, 5Ìbùkún ni fún ẹni tí Olúwa Ọlọ́run rẹ̀. 6Ẹni tí ó dá ọ̀run àti ayé, 7Ẹni tí ń ṣe ìdájọ́ àwọn tí a ni lára, Olúwa, tú àwọn oǹdè sílẹ̀, 8Olúwa mú àwọn afọ́jú ríran, Olúwa, gbé àwọn tí a rẹ̀ sílẹ̀ ga, Olúwa fẹ́ràn àwọn olódodo. 9Olúwa ń dá ààbò bo àwọn àlejò 10Olúwa jẹ ọba títí láé; Olúwa.

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →