YOR Psalm Chương 135

Psalm 135

YOR · So sánh · Âm thanh

1 yin Olúwa. Olúwa; Olúwa. 2Ẹ̀yin tí ń dúró ní ilé Olúwa, 3Ẹ yin Olúwa: nítorí tí Olúwa ṣeun; 4Nítorí tí Olúwa ti yan Jakọbu fún ara rẹ̀; 5Nítorí tí èmi mọ̀ pé Olúwa tóbi, 6Olúwa ṣe ohunkóhun tí ó wù ú, 7Ó mú ìkùùkuu gòkè láti òpin ilẹ̀ wá: 8Ẹni tí ó kọlu àwọn àkọ́bí Ejibiti, 9Ẹni tí ó rán iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu sí àárín rẹ̀, ìwọ Ejibiti, 10Ẹni tí ó kọlu àwọn orílẹ̀-èdè púpọ̀, 11Sihoni, ọba àwọn ará Amori, àti Ogu, 12Ó sì fi ilẹ̀ wọn fún ni ní ìní, 13Olúwa orúkọ rẹ dúró láéláé; Olúwa, láti ìrandíran. 14Nítorí tí Olúwa yóò ṣe ìdájọ́ àwọn ènìyàn rẹ̀, 15Fàdákà òun wúrà ni èrè àwọn aláìkọlà, 16Wọ́n ní ẹnu, ṣùgbọ́n wọn kò le sọ̀rọ̀; 17Wọ́n ní etí, ṣùgbọ́n wọn kò fi gbọ́rọ̀; 18Àwọn tí ń ṣe wọ́n dàbí wọn: 19Ẹ̀yin ara ilé Israẹli, ẹ fi ìbùkún fún Olúwa, Olúwa. 20Ẹ̀yin ará ilé Lefi, fi ìbùkún fún Olúwa; Olúwa, fi ìbùkún fún Olúwa. 21Olùbùkún ni Olúwa, láti Sioni wá, Olúwa.

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →