YOR Psalm Chương 4

Psalm 4

YOR · So sánh · Âm thanh

1Dá mi lóhùn nígbà tí mo bá pè ọ́, 2Báwo ni yóò ṣe pẹ́ tó, ẹ̀yin ọmọ ènìyàn, tí ẹ ó ṣe sọ ògo mi di ìtìjú? 3Ṣùgbọ́n kí ẹ mọ̀ pé, Olúwa ti ya ẹni olódodo sọ́tọ̀ fún ara rẹ̀; Olúwa yóò gbọ́ nígbà tí mo bá pè é. 4Ẹ bínú ẹ má ṣe ṣẹ̀, 5Ẹ rú ẹbọ òdodo Olúwa. 6Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ló ń béèrè pé, “Ta ni yóò ṣe rere fún wa?” Olúwa, jẹ́ kí ojú rẹ mọ́lẹ̀ sí wa lára, 7Ìwọ ti fi ayọ̀ púpọ̀ kún ọkàn mi 8Èmi yóò dùbúlẹ̀, èmi ó sì sùn ní àlàáfíà, Olúwa,

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →