YOR Psalm Chương 122

Psalm 122

YOR · So sánh · Âm thanh

1Inú mi dùn nígbà tí wọ́n wí fún mi pé, Olúwa.” 2Ẹsẹ̀ wa yóò dúró ní ẹnu ibodè rẹ, 3Jerusalẹmu, ìwọ tí a kọ́ bí ìlú 4Níbi tí àwọn ẹ̀yà máa ń gòkè lọ, Olúwa, Olúwa. 5Nítorí ibẹ̀ ni a gbé ìtẹ́ ìdájọ́ kalẹ̀, 6Gbàdúrà fún àlàáfíà Jerusalẹmu; 7Kí àlàáfíà kí ó wà nínú odi rẹ̀, 8Nítorí àwọn ọkùnrin àti àwọn ẹgbẹ́ mi 9Nítorí ilé Olúwa Ọlọ́run wa,

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →