Приче 28
1Ènìyàn búburú ń sá bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹnìkan kò lé e 2Nígbà tí orílẹ̀-èdè bá ní orí kunkun, àwọn ọba rẹ̀ a máa pọ̀, 3Ọba tí ó ni àwọn tálákà lára 4Àwọn tí ó kọ òfin sílẹ̀ a máa gbóríyìn fún ènìyàn búburú 5Òye ìdájọ́ òdodo kò yé àwọn ẹni ibi Olúwa dáradára. 6Ó sàn láti jẹ́ tálákà tí ìrìn rẹ̀ jẹ́ aláìlábùkù 7Ẹni tí ó pa òfin mọ́ jẹ́ olóye ọmọ 8Ẹni tí ó mú ọrọ̀ rẹ̀ di púpọ̀ nípa èrè àjẹjù 9Bí ẹnikẹ́ni bá kọ etí ikún sí òfin, 10Ẹni tí ó mú olódodo rìn ọ̀nà búburú 11Ọlọ́rọ̀ ènìyàn le è gbọ́n lójú ara rẹ̀ 12Nígbà tí olódodo ń lékè ariwo ayọ̀ ta; 13Ẹni tí ó bo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ mọ́lẹ̀ kì yóò ṣe rere, 14Ìbùkún ni fún ènìyàn náà tí ó bẹ̀rù Ọlọ́run nígbà gbogbo 15Bí kìnnìún tí ń ké tàbí Beari tí ń halẹ̀ 16Ọmọ-aládé tí ó ṣe aláìmòye púpọ̀ ní ń ṣe ìwà ìkà púpọ̀ pẹ̀lú, 17Ẹni tí ọkàn rẹ̀ kò balẹ̀ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ ìpànìyàn 18Ẹni tí ń rìn déédéé ní yóò là, 19Ẹni tí ó bá ro ilẹ̀ rẹ̀ yóò ní oúnjẹ lọ́pọ̀lọ́pọ̀ 20Olóòtítọ́ ènìyàn yóò rí ìbùkún gbà gan an 21Ojúsàájú ṣíṣe kò dára, 22Ahun ń sáré àti là 23Ẹni tí ó bá ènìyàn kan wí yóò rí ojúrere ni nígbẹ̀yìn 24Ẹni tí ó ja baba tàbí ìyá rẹ̀ lólè 25Ọ̀kánjúwà ènìyàn a máa dá ìjà sílẹ̀, Olúwa yóò gbilẹ̀. 26Ẹni tí ó gbẹ́kẹ̀lé ara rẹ̀ jẹ́ aláìgbọ́n 27Ẹni tí ó ń fi fún tálákà kì yóò ṣe aláìní ohunkóhun, 28Nígbà tí ènìyàn búburú bá dórí ìjọba, àwọn ènìyàn a na pápá bora;