YOR Приче Poglavlje 12

Приче 12

YOR · Uporedi · Audio

1nikẹ́ni tí ó fẹ́ ẹ̀kọ́ fẹ́ ìmọ̀, 2Ènìyàn rere gba ojúrere lọ́dọ̀ Olúwa 3A kò lè fi ẹsẹ̀ ènìyàn múlẹ̀ nípa ìwà búburú 4Aya oníwà rere ni adé ọkọ rẹ̀ 5Èrò àwọn olódodo tọ́, 6Ọ̀rọ̀ ènìyàn búburú lúgọ de ẹ̀jẹ̀ 7A ṣí àwọn ènìyàn búburú ní ìdí, wọn kò sì sí mọ́; 8A ń yín ènìyàn gẹ́gẹ́ bí ìwọ̀n ọgbọ́n rẹ̀ 9Ó sàn kí a má jẹ́ ènìyàn pàtàkì kí a sì ní ìránṣẹ́ 10Olódodo ènìyàn ń ṣe aájò ohun tí àwọn ohun ọ̀sìn rẹ̀ nílò, 11Ẹni tí ó bá dá oko yóò ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ oúnjẹ, 12Ènìyàn búburú ń fẹ́ ìkógun àwọn ènìyàn ìkà 13A mú ènìyàn búburú nípasẹ̀ ọ̀rọ̀ ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ 14Láti inú èso rẹ̀, ènìyàn kún fún onírúurú ohun rere 15Ọ̀nà aláìgbọ́n dára lójú ara rẹ̀ 16Aláìgbọ́n ènìyàn fi ìbínú un rẹ̀ hàn lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, 17Ẹni tí ó jẹ́ ajẹ́rìí òtítọ́ jẹ́rìí ohun tí ojú rẹ̀ rí 18Ọ̀rọ̀ tí a kò rò jinlẹ̀ máa ń gún ni bí ọ̀kọ̀ 19Ètè tí ń ṣọ òtítọ́ yóò wà láéláé 20Ẹ̀tàn wà nínú ọkàn àwọn tí ń pète búburú 21Ibi kì í ṣubú lu olódodo rárá 22Olúwa kórìíra ètè tí ń parọ́ 23Ènìyàn olóye fi ìmọ̀ rẹ̀ pamọ́ sínú ara rẹ̀ 24Ọwọ́ àìṣọ̀lẹ yóò jẹ ọba 25Ìbànújẹ́ ní ọkàn ènìyàn ní dorí rẹ̀ kodò 26Olódodo ènìyàn máa ń ṣọ́ra láti dọ́rẹ̀ẹ́ 27Ọ̀lẹ ènìyàn kò sun ẹran tí ó pa lóko ọdẹ 28Ní ọ̀nà àwọn olódodo ni ìyè wà