YOR Приче Poglavlje 14

Приче 14

YOR · Uporedi · Audio

1lọ́gbọ́n obìnrin kọ́ ilé e rẹ̀, 2Ẹni tí ń rìn déédé bẹ̀rù Olúwa, Olúwa. 3Ọ̀rọ̀ aṣiwèrè a máa ṣokùnfà pàṣán fún ẹ̀yìn rẹ̀, 4Níbi tí kò sí ẹran, ibùjẹ ẹran a máa mọ́ tónítóní, 5Ẹlẹ́rìí tí ń ṣọ òtítọ́ kì í tan ni 6Ẹlẹ́gàn ń wá ọgbọ́n kò sì rí rárá, 7Má ṣe súnmọ́ aláìgbọ́n ènìyàn, 8Ọgbọ́n olóye ni láti ronú jinlẹ̀ nípa ọ̀nà wọn 9Aláìgbọ́n ń dẹ́ṣẹ̀ nígbà tí ó yẹ kí ó ṣe àtúnṣe ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ 10Ọkàn kọ̀ọ̀kan ló mọ ẹ̀dùn ọkàn tirẹ̀ 11A ó pa ilé ènìyàn búburú run, 12Ọ̀nà kan wà tí ó dàbí i pé ó dára lójú ènìyàn, 13Kódà nígbà tí a ń rẹ́rìn-ín, ọkàn le è máa kérora; 14A ó san án lẹ́kùnrẹ́rẹ́ fún aláìgbàgbọ́ gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà rẹ̀, 15Òpè ènìyàn gba ohun gbogbo gbọ́ 16Ọlọ́gbọ́n bẹ̀rù Ọlọ́run ó sì kórìíra ibi 17Ẹni tí ó máa ń tètè bínú máa ń hùwà aṣiwèrè, 18Òpè jogún ìwà òmùgọ̀ 19Ènìyàn ìkà yóò tẹríba níwájú àwọn ènìyàn rere 20Kódà àwọn aládùúgbò tálákà kò fẹ́ràn rẹ̀, 21Ẹni tí ó kẹ́gàn aládùúgbò o rẹ̀ ti dẹ́ṣẹ̀ 22Ǹjẹ́ àwọn tí ń pète ibi kì í ṣìnà bí? 23Gbogbo iṣẹ́ àṣekára ló máa ń mú èrè wá, 24Ọrọ̀ ọlọ́gbọ́n ènìyàn ni adé orí wọn 25Ẹlẹ́rìí tí ó ṣọ òtítọ́ gba ẹ̀mí là 26Nínú ìbẹ̀rù Olúwa ni ìgbẹ́kẹ̀lé tí ó lágbára, 27Ìbẹ̀rù Olúwa jẹ́ orísun ìyè, 28Ènìyàn púpọ̀ ní ìlú jẹ́ ògo ọba, 29Onísùúrù ènìyàn ní òye tí ó pọ̀, 30Ọkàn tí ó lálàáfíà fi ìyè mú kí ọjọ́ ayé gùn fún ara, 31Ẹni tí ó fi ìyà jẹ aláìní ń fi ìkórìíra hàn 32Nígbà tí ìyọnu bá dé, a fa àwọn búburú lulẹ̀, 33Ọgbọ́n wà nínú ọkàn olóye 34Òdodo a máa gbé orílẹ̀-èdè lékè, 35Ọba a máa ní inú dídùn sí ìránṣẹ́ tí ó gbọ́n