YOR Приче Poglavlje 10

Приче 10

YOR · Uporedi · Audio

1Àwọn òwe Solomoni. 2Ìṣúra tí a kójọ nípa ìwà búburú kò ní èrè, 3Olúwa kì í jẹ́ kí ebi máa pa olódodo, 4Ọwọ́ tí ó lẹ máa ń sọ ènìyàn di tálákà, 5Ẹni tí ó kó irúgbìn jọ ní àsìkò òjò jẹ́ ọlọ́gbọ́n ọmọ, 6Ìbùkún ní ó máa ń kún orí olódodo, 7Ìrántí olódodo yóò jẹ́ ìbùkún, 8Ẹni tí ó gbọ́n nínú ọkàn rẹ̀ máa ń gba àṣẹ, 9Ẹni tí ó ń rìn déédé, ń rìn láìléwu, 10Ẹni tí ń ṣẹ́jú pàkòpàkò fún ibi ń fa àìbalẹ̀ ọkàn, 11Ẹnu olódodo jẹ́ orísun ìyè, 12Ìríra a máa dá ìjà sílẹ̀, 13Ọgbọ́n ni a ń bá lẹ́nu àwọn olóye, 14Ọlọ́gbọ́n ènìyàn kó ìmọ̀ jọ, 15Ọrọ̀ àwọn olódodo ni ìlú olódi wọn, 16Èrè olódodo ń mú ìyè wá fún wọn, 17Ẹni tí ó gbọ́ ìbáwí fi ọ̀nà sí ìyè hàn, 18Ẹni tí ó pa ìkórìíra rẹ̀ mọ́ jẹ́ òpùrọ́ 19Nínú ọ̀rọ̀ púpọ̀ a kò le fẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ kù 20Ètè olódodo jẹ́ ààyò fàdákà, 21Ètè olódodo ń bọ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀, 22Ìbùkún Olúwa ń mú ọrọ̀ wá, 23Aláìgbọ́n a máa ní inú dídùn sí ìwà búburú, 24Ohun tí ènìyàn búburú bẹ̀rù yóò dé bá a; 25Nígbà tí ìjì bá ti jà kọjá, ènìyàn búburú a kọjá lọ, 26Bí ọtí kíkan sí eyín, àti èéfín sí ojú, 27Ìbẹ̀rù Olúwa ń mú ọjọ́ ayé gígùn wá, 28Ìrètí olódodo ni ayọ̀, 29Ọ̀nà Olúwa jẹ́ ààbò fún olódodo, 30A kì yóò fa olódodo tu láéláé, 31Ẹnu olódodo ń mú ọgbọ́n jáde wá, 32Ètè olódodo mọ ohun ìtẹ́wọ́gbà,