YOR Psalm 章 74

Psalm 74

YOR · 比較 · 音声

1lọ́run, èéṣe tí ìwọ fi kọ̀ wá sílẹ̀ títí láé? 2Rántí àwọn ènìyàn tí ìwọ ti rà nígbà àtijọ́, 3Yí ẹsẹ̀ rẹ padà sí ìparun ayérayé wọn, 4Àwọn ọ̀tá rẹ ń bú ramúramù 5Wọ́n ń rí bí ọkùnrin tí ó gbé àáké rẹ̀ sókè 6Ṣùgbọ́n nísinsin yìí, iṣẹ́ ọnà fínfín, 7Wọ́n sun ibi mímọ́ rẹ lulẹ̀ 8Wọ́n wí ní ọkàn wọn. “Àwa ó run wọ́n pátápátá!” 9A kò fún wa ní àmì iṣẹ́ ìyanu kankan; 10Àwọn ọ̀tá yóò ti kùn sí ọ pẹ́ tó, Ọlọ́run? 11Èéṣe tí ìwọ fi dá ọwọ́ rẹ dúró, ọwọ́ ọ̀tún rẹ? 12Ṣùgbọ́n ìwọ Ọlọ́run ni ọba mi láti ìgbà pípẹ́; 13Ìwọ ni ó la òkun sílẹ̀ nípa agbára rẹ; 14Ìwọ fọ́ orí Lefitani túútúú, o sì fi ṣe oúnjẹ fun àwọn ẹ̀dá tí ń gbé inú ijù 15Ìwọ ya orísun omi àti ìṣàn omi; 16Tìrẹ ni ọ̀sán, tìrẹ ni òru pẹ̀lú; 17Ìwọ pààlà etí ayé; 18Rántí bí àwọn ọ̀tá ń kẹ́gàn rẹ, Olúwa 19Má ṣe fi ẹ̀mí àdàbà rẹ fún ẹranko igbó búburú; 20Bojú wo májẹ̀mú rẹ, 21Má ṣe jẹ́ kí àwọn aninilára padà sẹ́yìn nínú ìtìjú 22Dìde, Ọlọ́run, gba ẹjọ́ ara rẹ rò; 23Má ṣe gbàgbé ohùn àwọn ọ̀tá rẹ,

1日の制限に達しました

プランをアップグレードして、より高い1日の制限でAI機能を使い続けてください。

すべてのプランを比較 →