YOR Psalm 章 52

Psalm 52

YOR · 比較 · 音声

1Èéṣe tí ìwọ fi ń ṣe féfé nínú ìwà ìkà, ìwọ alágbára ọkùnrin? 2Ahọ́n rẹ̀ ń gbìmọ̀ ìparun; 3Ìwọ fẹ́ràn ibi ju ìre lọ, 4Ìwọ fẹ́ràn ọ̀rọ̀ ìpanilára gbogbo, 5Ọlọ́run yóò sì lù ọ́ bolẹ̀ láéláé, Sela. 6Àwọn olódodo yóò rí, wọn yóò sì bẹ̀rù 7“Èyí ni ọkùnrin náà ti kò fi Ọlọ́run ṣe agbára rẹ̀, 8Ṣùgbọ́n èmi dàbí igi Olifi 9Èmi yóò yìn ọ títí fún ohun tí ó ti ṣe;

1日の制限に達しました

プランをアップグレードして、より高い1日の制限でAI機能を使い続けてください。

すべてのプランを比較 →