YOR Psalm 章 128

Psalm 128

YOR · 比較 · 音声

1Ìbùkún ni fún gbogbo ẹni tí ó bẹ̀rù Olúwa: 2Nítorí tí ìwọ yóò jẹ iṣẹ́ ọwọ́ rẹ 3Obìnrin rẹ yóò dàbí àjàrà rere 4Kíyèsi i pé, bẹ́ẹ̀ ni a ó bùsi i fún ọkùnrin náà, Olúwa. 5Kí Olúwa kí ó bùsi i fún ọ láti Sioni wá, 6Bẹ́ẹ̀ ni kí ìwọ kí ó sì máa rí àti ọmọdọ́mọ rẹ.

1日の制限に達しました

プランをアップグレードして、より高い1日の制限でAI機能を使い続けてください。

すべてのプランを比較 →