YOR Psalm 章 27

Psalm 27

YOR · 比較 · 音声

1Olúwa ni ìmọ́lẹ̀ mi àti ìgbàlà mi; Olúwa ni ibi ìsádi ẹ̀mí mi, 2Nígbà tí àwọn ènìyàn búburú kọjú ìjà sí mi 3Bí ọmọ-ogun tilẹ̀ yí mi ká tí wọ́n sì dìde sí mi, 4Ohun kan ni mo béèrè lọ́dọ̀ Olúwa, Olúwa Olúwa, 5Nítorí pé ní ìgbà ìpọ́njú 6Ní ìsinsin yìí, a ti gbé orí mi sókè Olúwa. 7Gbọ́ ohùn mi nígbà tí ẹ̀mí bá à ń pè, Olúwa, 8Ọkàn mi wí pé, “Wá ojú u rẹ̀!” Olúwa, ni ti èmí ń wá. 9Má ṣe fi ojú rẹ pamọ́ kúrò lọ́dọ̀ mi, 10Bí ìyá àti baba bá kọ̀ mí sílẹ̀, Olúwa yóò tẹ́wọ́ gbà mí. 11Kọ́ mi ní ọ̀nà rẹ, Olúwa, 12Má ṣe fi mí lé ìfẹ́ àwọn ọ̀tá mi lọ́wọ́, 13Èmi ní ìgbàgbọ́ pé, Olúwa 14Dúró de Olúwa; Olúwa.

1日の制限に達しました

プランをアップグレードして、より高い1日の制限でAI機能を使い続けてください。

すべてのプランを比較 →