YOR Psalm 章 51

Psalm 51

YOR · 比較 · 音声

1àánú fún mi, Ọlọ́run, 2Wẹ gbogbo àìṣedéédéé mi nù kúrò 3Nítorí mo mọ̀ gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ mi, 4Sí ọ, ìwọ nìkan ṣoṣo, ni mo dẹ́ṣẹ̀ sí 5Nítòótọ́, nínú ẹ̀ṣẹ̀ ni a ti bí mi, 6Nítòótọ́ ìwọ fẹ́ òtítọ́ ní inú; 7Wẹ̀ mí pẹ̀lú ewé hísópù, èmi yóò sì mọ́; 8Jẹ́ kí n gbọ́ ayọ̀ àti inú dídùn; 9Pa ojú rẹ̀ mọ́ kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ mi 10Dá ọkàn mímọ́ sí inú mi, Ọlọ́run, 11Má ṣe jù mi nù kúrò níwájú rẹ, 12Mú ayọ̀ ìgbàlà rẹ tọ̀ mí wá, 13Nígbà náà ni èmi yóò máa kọ́ àwọn olùrékọjá ní ọ̀nà rẹ, 14Gbà mí kúrò lọ́wọ́ ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀, Ọlọ́run, 15Olúwa, ṣí mi ní ètè mi gbogbo, 16Nítorí ìwọ kò ní inú dídùn sí ẹbọ, tí èmi kò bá mú wá; 17Ẹbọ Ọlọ́run ni ìròbìnújẹ́ ọkàn ìròbìnújẹ́ àti ìrora àyà. 18Ṣe rere ní dídùn inú rẹ sí Sioni, 19Nígbà náà ni inú rẹ yóò dùn sí ẹbọ òdodo,

1日の制限に達しました

プランをアップグレードして、より高い1日の制限でAI機能を使い続けてください。

すべてのプランを比較 →