YOR Psalm 章 21

Psalm 21

YOR · 比較 · 音声

1Háà! Olúwa, ọba yóò yọ̀ nínú agbára rẹ, 2Nítorí pé ìwọ ti fi ìfẹ́ ọkàn rẹ̀ fún un, Sela. 3Ìwọ ti fi àwọn ìbùkún oore kò ó ni ọ̀nà 4Ó béèrè fún ìyè, ìwọ sì fi fún un, 5Ògo rẹ̀ pọ̀ nípasẹ̀ ìṣẹ́gun tí o fi fún un; 6Dájúdájú, ìwọ ti fi ìbùkún ayérayé fún un: 7Ọba ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú Olúwa; 8Ọwọ́ rẹ yóò wá gbogbo àwọn ọ̀tá a rẹ rí; 9Nígbà tí ìwọ bá yọ Olúwa yóò gbé wọn mì nínú ìbínú rẹ̀, 10Ìwọ yóò pa ìrandíran wọn run kúrò lórí ilẹ̀, 11Bí o tilẹ̀ jẹ́ wí pé wọ́n ro èrò ibi sí ọ 12Nítorí pé ìwọ yóò mú wọn yí ẹ̀yìn wọn padà 13Gbígbéga ni ọ́ Olúwa, nínú agbára rẹ;

1日の制限に達しました

プランをアップグレードして、より高い1日の制限でAI機能を使い続けてください。

すべてのプランを比較 →