YOR Ησαΐας Κεφάλαιο 65

Ησαΐας 65

1Èmi fi ara mi hàn fún àwọn tí kò béèrè fún mi; 2Gbogbo ọjọ́ ni mo ti nawọ́ mi síta 3àwọn ènìyàn tí wọ́n bí mi nínú nígbà gbogbo 4wọ́n ń jókòó láàrín ibojì 5tí ó wí pé, ‘Ẹ sún mẹ́yìn; ẹ má wá sọ́dọ̀ mi, 6“Kíyèsi i, a ti kọ ọ́ síwájú mi, 7àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín àti tàwọn baba yín,” Olúwa wí. 8Báyìí ni Olúwa wí: 9Èmi yóò mú ìrandíran wá láti ìdílé Jakọbu, 10Ṣaroni yóò di pápá oko fún ọ̀wọ́ ẹran, 11“Ṣùgbọ́n fún ẹ̀yin tí ó kọ Olúwa sílẹ̀ 12Èmi yóò yà ọ́ sọ́tọ̀ fún idà, 13Nítorí náà, báyìí ni Olúwa Olódùmarè wí: 14Àwọn ìránṣẹ́ mi yóò kọrin 15Ẹ̀yin yóò fi orúkọ yín sílẹ̀ Olúwa Olódùmarè yóò sì pa yín, 16Ẹnikẹ́ni tí ó bá gbàdúrà ìbùkún ní ilẹ̀ náà 17“Kíyèsi i, Èmi yóò dá 18Ṣùgbọ́n ẹ yọ̀ kí inú yín dùn títí láé 19Èmi yóò ṣe àjọyọ̀ lórí Jerusalẹmu 20“Títí láé a kì yóò gbọ́ nínú rẹ̀ 21Wọn yó ò kọ́ ilé, wọn yóò sì gbé nínú wọn 22Wọn kì yóò kọ́ ilé fún ẹlòmíràn láti gbé, 23Wọn kì yóò ṣe iṣẹ́ lásán, Olúwa bùkún fún, 24Kí wọn tó pè, èmi yóò dáhùn; 25Ìkookò àti ọ̀dọ́-àgùntàn yóò jẹun pọ̀, Olúwa wí.

Ημερήσιο Όριο Φτάσιμο

Αναβαθμίστε το πακέτο σας για να συνεχίσετε να χρησιμοποιείτε τις λειτουργίες ΑΙ με υψηλότερα ημερήσια όρια.

Σύγκριση όλων των προγραμμάτων →