YOR Ησαΐας Κεφάλαιο 54

Ησαΐας 54

1Kọrin, ìwọ obìnrin àgàn, Olúwa wí. 2Fẹ ibi àgọ́ rẹ lójú sí i, 3Nítorí ìwọ ó fẹ̀ sọ́tùn àti sí òsì; 4“Má ṣe bẹ̀rù, ìtìjú kò ní ṣubú lù ọ́. 5Nítorí Ẹlẹ́dàá rẹ ni ọkọ rẹ Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni orúkọ rẹ̀ 6Olúwa yóò pè ọ́ padà Olúwa wí. 7“Fún ìgbà díẹ̀ ni mo kọ̀ ọ́ sílẹ̀, 8Ní ríru ìbínú. Olúwa Olùdáǹdè rẹ wí. 9“Sí mi, èyí dàbí i àwọn ọjọ́ Noa, 10Bí a tilẹ̀ mi àwọn òkè ńlá Olúwa, ẹni tí ó síjú àánú wò ọ́ wí. 11Ìwọ ìlú tí a pọ́n lójú, tí ìjì ń gbá kiri 12Èmi yóò fi iyùn ṣe odi rẹ, 13Gbogbo ọ̀dọ́mọkùnrin rẹ ni Olúwa yóò kọ́, 14Ní òdodo ni a ó fi ìdí rẹ kalẹ̀ 15Bí ẹnikẹ́ni bá tilẹ̀ bá ọ jà, kò ní jẹ́ láti ọwọ́ mi; 16“Kíyèsi i, èmi ni ó dá alágbẹ̀dẹ 17kò sí ohun ìjà tí a ṣe sí ọ tí yóò lè ṣe nǹkan, Olúwa, Olúwa wí.

Ημερήσιο Όριο Φτάσιμο

Αναβαθμίστε το πακέτο σας για να συνεχίσετε να χρησιμοποιείτε τις λειτουργίες ΑΙ με υψηλότερα ημερήσια όρια.

Σύγκριση όλων των προγραμμάτων →