Ησαΐας 33
1Ègbé ni fún ọ, ìwọ apanirun, 2Olúwa ṣàánú fún wa 3Ní ìkérara ohùn rẹ, àwọn ènìyàn sá, 4Ìkógun rẹ, ìwọ orílẹ̀-èdè ni a kórè 5A gbé Olúwa ga, nítorí pé ó ń gbé ibi gíga, 6Òun yóò jẹ́ ìpìlẹ̀ tí ó dájú fún àkókò rẹ Olúwa ni kọ́kọ́rọ́ sí ìṣúra yìí. 7Wò ó, àwọn onígboyà ọkùnrin wọn pohùnréré 8Àwọn ojú ọ̀nà ńlá ni a ṣá tì, 9Ilẹ̀ ṣọ̀fọ̀ ó sì ṣòfò dànù, 10“Ní ìsinsin yìí ni èmi yóò dìde,” ni Olúwa wí. 11Ìwọ lóyún ìyàngbò, 12A ó jó àwọn ènìyàn run bí eérú; 13Ìwọ tí ó wà lọ́nà jíjìn, gbọ́ ohun tí mo ti ṣe; 14Ẹ̀rù ba àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ní Sioni; 15Ẹni tí ó ń rìn lódodo 16Òun náà yóò gbé ní ibi gíga, 17Ojú rẹ yóò rí ọba nínú ẹwà rẹ̀ 18Nínú èrò rẹ ìwọ yóò rántí ẹ̀rù rẹ àtẹ̀yìnwá: 19Ìwọ kì yóò rí àwọn agbéraga ènìyàn mọ́, 20Gbójú sókè sí Sioni, ìlú àjọ̀dún wa, 21Níbẹ̀ ni Olúwa yóò ti jẹ́ alágbára kan fún wa. 22Nítorí Olúwa ni onídàájọ́ wa, Olúwa ni onídàájọ́ wa, Olúwa òun ni ọba wa; 23Gbogbo okùn rẹ ni ó ti dẹ̀: 24Kò sí ẹnikẹ́ni tí ó ń gbé Sioni tí yóò wí pé, “Ara mi kò yá,”