YOR Ησαΐας Κεφάλαιο 60

Ησαΐας 60

1Dìde, tànmọ́lẹ̀, nítorí ìmọ́lẹ̀ rẹ ti dé, Olúwa sì ràdàbò ọ́. 2Kíyèsi i, òkùnkùn bo ilẹ̀ ayé Olúwa ràn bò ọ́ 3Àwọn orílẹ̀-èdè yóò wá sí ìmọ́lẹ̀ rẹ, 4“Gbé ojú rẹ sókè, kí o sì wò. 5Nígbà náà ni ìwọ yóò wò tí ojú rẹ yóò máa dán, 6Ọ̀wọ́ ìbákasẹ yóò bo gbogbo ilẹ̀ rẹ, Olúwa. 7Gbogbo agbo ẹran ìlú Kedari ni a ó kójọ sọ́dọ̀ rẹ, 8“Ta ni àwọn wọ̀nyí tí ń fò lọ bí i kurukuru, 9Lóòtítọ́ àwọn erékùṣù bojú wò mí; Olúwa Ọlọ́run rẹ, 10“Àwọn àjèjì yóò tún ògiri rẹ mọ 11Gbogbo ẹnu-bodè rẹ ni yóò wà ní ṣíṣí sílẹ̀, 12Nítorí pé orílẹ̀-èdè tàbí ilẹ̀ ọba tí kì yóò sìn ọ́ ni yóò parun; 13“Ògo Lebanoni yóò wá sí ọ̀dọ̀ rẹ, 14Àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin àwọn apọ́nilójú rẹ yóò Olúwa, 15“Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a ti kórìíra rẹ, a sì kọ̀ ọ́ sílẹ̀, 16Ìwọ yóò mu wàrà gbogbo orílẹ̀-èdè Olúwa, 17Dípò idẹ, èmi ó mú wúrà wá fún ọ, 18A kì yóò gbọ́ nípa rògbòdìyàn ní ilẹ̀ rẹ mọ́, 19Òòrùn kì yóò sì jẹ́ ìmọ́lẹ̀ rẹ ní ọ̀sán mọ́, Olúwa ni yóò jẹ́ ìmọ́lẹ̀ rẹ ayérayé, 20Òòrùn rẹ kì yóò sì wọ̀ mọ́, Olúwa ni yóò jẹ́ ìmọ́lẹ̀ ayérayé rẹ, 21Lẹ́yìn náà ni gbogbo àwọn ènìyàn rẹ yóò di òdodo 22Èyí tí ó kéré jù nínú yín yóò di ẹgbẹ̀rún (1,000) kan, Olúwa;

Ημερήσιο Όριο Φτάσιμο

Αναβαθμίστε το πακέτο σας για να συνεχίσετε να χρησιμοποιείτε τις λειτουργίες ΑΙ με υψηλότερα ημερήσια όρια.

Σύγκριση όλων των προγραμμάτων →