YOR Ησαΐας Κεφάλαιο 29

Ησαΐας 29

1Ègbé ni fún ọ, Arieli, Arieli, 2Síbẹ̀síbẹ̀ èmi yóò dó ti Arieli 3Èmi yóò sì wà ní bùba yí ọ ká níbi gbogbo, 4Ní ìrẹ̀sílẹ̀, ìwọ ó sì máa sọ̀rọ̀ láti ilẹ̀ wá; 5Ṣùgbọ́n àwọn ọ̀tá rẹ, yóò dàbí yanrìn kíkúnná, 6Olúwa àwọn ọmọ-ogun yóò wá 7Lẹ́yìn náà, 8àti bí ìgbà tí ẹni tí ebi ń pa ń lá àlá pé òun ń jẹun, 9Ẹ bẹ̀rù kí ẹnu kí ó yà yín, 10Olúwa ti mú oorun ìjìká wá sórí i yín: 11Fún un yín gbogbo ìran yìí kò yàtọ̀ sí àwọn ọ̀rọ̀ tí a fi èdìdì dì sínú ìwé kíká. Bí ẹ bá sì fún ẹni tí ó lè ka ìwé kíká náà, tí ẹ sì sọ fún un pé, “Jọ̀wọ́ ka èyí,” òun yóò dáhùn pé, “Èmi kò lè kà á; a ti dì í ní èdìdì.” 12Tàbí bí ẹ bá fún ẹni tí kò lè ka ìwé kíká náà tí ẹ sì sọ pé, “Jọ̀wọ́ ka èyí,” òun yóò dáhùn pé, “Èmi kò mọ̀ ọ́n kà.” 13Olúwa wí pé: 14Nítorí náà lẹ́ẹ̀kan sí i èmi yóò ya 15Ègbé ni fún àwọn tí ó lọ sí ọ̀gbun Olúwa, 16Ẹ̀yin dojú nǹkan délẹ̀, 17Ní àìpẹ́ jọjọ, ǹjẹ́ 18Ní ọjọ́ náà adití yóò gbọ́ ọ̀rọ̀ ìwé kíká náà, 19Lẹ́ẹ̀kan sí i àwọn onírẹ̀lẹ̀ yóò yọ̀ nínú Olúwa: 20Aláìláàánú yóò pòórá, 21àwọn tí wọ́n fi ọ̀rọ̀ kan mú ẹnìkan di ẹlẹ́bi, 22Nítorí náà, èyí ni ohun tí Olúwa, ẹni tí ó ra Abrahamu padà sọ sí ilé Jakọbu: 23Nígbà tí wọ́n bá rí i láàrín àwọn ọmọ wọn, 24Gbogbo àwọn tí ń rìn ségesège ní yóò jèrè ìmọ̀;

Ημερήσιο Όριο Φτάσιμο

Αναβαθμίστε το πακέτο σας για να συνεχίσετε να χρησιμοποιείτε τις λειτουργίες ΑΙ με υψηλότερα ημερήσια όρια.

Σύγκριση όλων των προγραμμάτων →