YOR Isaiah 章 62

Isaiah 62

YOR · 比較 · 音声

1Nítorí Sioni èmi kì yóò dákẹ́, 2Àwọn orílẹ̀-èdè yóò rí òdodo rẹ, Olúwa yóò fi fún un. 3Ìwọ yóò sì jẹ́ adé dídán ní ọwọ́ Olúwa, 4Wọn kì yóò pè ọ́ ní ìkọ̀sílẹ̀ mọ́ Olúwa yóò yọ́nú sí ọ 5Gẹ́gẹ́ bí ọ̀dọ́mọkùnrin tí í gbé ọ̀dọ́mọbìnrin níyàwó, 6Èmi ti fi olùṣọ́ ránṣẹ́ sórí odi rẹ ìwọ Jerusalẹmu; Olúwa, 7àti kí ẹ má ṣe fún òun pẹ̀lú ní ìsinmi 8Olúwa ti búra pẹ̀lú ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ 9ṣùgbọ́n àwọn tí ó bá kóórè rẹ̀ ni yóò jẹ ẹ́, Olúwa, 10Ẹ kọjá, ẹ kọjá ní ẹnu ibodè náà! 11Olúwa ti ṣe ìkéde 12A ó sì pè wọ́n ní Ènìyàn Mímọ́, Olúwa;

1日の制限に達しました

プランをアップグレードして、より高い1日の制限でAI機能を使い続けてください。

すべてのプランを比較 →