YOR Isaiah 章 31

Isaiah 31

YOR · 比較 · 音声

1Ègbé ni fún àwọn tí ó sọ̀kalẹ̀ lọ sí Olúwa. 2Síbẹ̀síbẹ̀ òun pẹ̀lú jẹ́ ọlọ́gbọ́n ó sì lè mú ìparun wá; 3Ṣùgbọ́n ènìyàn lásán ni àwọn ará Ejibiti Olúwa bá na ọwọ́ rẹ̀ jáde, 4Èyí ni ohun tí Olúwa sọ fún mi: Olúwa àwọn ọmọ-ogun yóò sọ̀kalẹ̀ wá 5Gẹ́gẹ́ bí àwọn ẹyẹ ti ń rábàbà lókè Olúwa àwọn ọmọ-ogun yóò dáàbò bo Jerusalẹmu, 6Ẹ padà sọ́dọ̀ ẹni tí ẹ ti ṣọ̀tẹ̀ sí gidigidi, ẹ̀yin ọmọ Israẹli. 7Nítorí ní ọjọ́ náà, ẹnìkọ̀ọ̀kan yín yóò kọ àwọn ère fàdákà àti wúrà tí ọwọ́ ẹ̀ṣẹ̀ yín ti ṣe. 8“Asiria yóò ṣubú lọ́wọ́ idà kan tí kò ti ọwọ́ ènìyàn wá; 9Àpáta rẹ yóò kọjá lọ fún ẹ̀rù; Olúwa wí,

1日の制限に達しました

プランをアップグレードして、より高い1日の制限でAI機能を使い続けてください。

すべてのプランを比較 →