YOR Isaiah 章 3

Isaiah 3

YOR · 比較 · 音声

1Kíyèsi i, Olúwa, Olúwa àwọn ọmọ-ogun, 2Àwọn akíkanjú àti jagunjagun, 3balógun àádọ́ta àti àwọn ènìyàn, onípò gíga; 4“Èmi ó sọ àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin di aláṣẹ wọn, 5Àwọn ènìyàn yóò sì máa pọ́n ọmọnìkejì, 6Ọkùnrin kan yóò di ọ̀kan nínú àwọn 7Ṣùgbọ́n ní ọjọ́ náà ni yóò figbe bọnu pé, 8Jerusalẹmu ń ta gbọ̀nọ́ngbọ̀nọ́n Olúwa, 9Ìwò ojú wọn ń jẹ́rìí lòdì sí wọn, 10Ẹ sọ fún olódodo pé yóò dára fún wọn, 11Ègbé ni fún ènìyàn búburú! Ìparun wà lórí i wọn, 12Àwọn ọ̀dọ́mọdé ni o ń pọ́n àwọn ènìyàn mi lójú 13Olúwa bọ sí ipò rẹ̀ ní ìtẹ́ ìdájọ́ 14Olúwa dojú ẹjọ́ kọ 15Kín ni èrò yín láti máa run àwọn ènìyàn mi túútúú Olúwa àwọn ọmọ-ogun. 16Olúwa wí pé, 17Nítorí náà Olúwa yóò mú egbò wá sórí àwọn obìnrin Sioni, Olúwa yóò sì pá wọn ní agbárí.” 18Ní ọjọ́ náà, Olúwa yóò já ọ̀ṣọ́ wọn gbà kúrò ti ọwọ́ àti gèlè àti ẹ̀gbà ọrùn tí ó dàbí òṣùpá 19gbogbo yẹtí, ẹ̀gbà ọwọ́ àti ìbòjú, 20gbogbo gèlè, ẹ̀gbà ọrùn, ẹsẹ̀ àti àyà, àwọn ìgò tùràrí àti òògùn, 21òrùka ọwọ́ àti ti imú, 22àwọn àtàtà aṣọ, àwọ̀lékè, agbádá àti àpamọ́wọ́, 23dígí wọn, aṣọ funfun nigínnigín ìbòrí àti ìbòjú. 24Dípò òórùn dídùn, òórùn búburú ni yóò wá, 25Àwọn ọkùnrin rẹ yóò ti ipa idà ṣubú, 26Àwọn bodè Sioni yóò sọkún kíkorò, wọn ó ṣọ̀fọ̀,

1日の制限に達しました

プランをアップグレードして、より高い1日の制限でAI機能を使い続けてください。

すべてのプランを比較 →