Zsoltárok 65
1Ìyìn ń dúró dè ọ́, Ọlọ́run, ní Sioni; 2Ìwọ tí ó ń gbọ́ àdúrà, 3Ọ̀ràn àìṣedéédéé borí mi bí ó ṣe ti ìrékọjá wa ni! 4Ìbùkún ni fún àwọn tí o yàn 5Ìwọ dá wa lóhùn pẹ̀lú ohun ìyanu ti òdodo, 6ìwọ tí ó dá òkè nípa agbára rẹ, 7ẹni tí ó mú rírú omi òkun dákẹ́, 8Àwọn tí ó ń gbé òkèrè bẹ̀rù, 9Ìwọ bẹ ayé wò, o sì bomirin; 10Ìwọ fi bomirin sí aporo rẹ̀ 11Ìwọ fi oore rẹ dé ọdún ní adé, 12Pápá tútù ní aginjù ń kan 13Agbo ẹran ni a fi wọ pápá tútù náà ní aṣọ;