Zsoltárok 2
1Èéṣe tí àwọn orílẹ̀-èdè fi ń dìtẹ̀, 2Àwọn ọba ayé péjọpọ̀ Olúwa àti sí ẹni àmì òróró rẹ̀. 3Wọ́n sọ pé, “Ẹ jẹ́ kí a fa ẹ̀wọ̀n wọn já, 4Ẹni tí ó gúnwà lórí ìtẹ́ lọ́run rẹ́rìn-ín; 5Nígbà náà ni yóò bá wọn wí ní ìbínú rẹ̀ 6“Èmi ti fi ọba mi sí ipò 7Èmi yóò sì kéde ìpinnu Olúwa: 8Béèrè lọ́wọ́ mi, 9Ìwọ yóò fi ọ̀pá irin ṣe àkóso wọn 10Nítorí náà, ẹ̀yin ọba, ẹ jẹ́ ọlọ́gbọ́n; 11Ẹ sin Olúwa pẹ̀lú ìbẹ̀rù 12Fi ẹnu ko ọmọ náà ní ẹnu, kí ó má ba à bínú,