YOR Zsoltárok Fejezet 64

Zsoltárok 64

YOR · Összevetés · Hang

1Gbóhùn mi, Ọlọ́run, bí mo ti ń sọ àròyé mi 2Pa mí mọ́ kúrò lọ́wọ́ ìmọ̀ ìkọ̀kọ̀ àwọn ènìyàn búburú 3Wọ́n pọ́n ahọ́n wọn bí idà, 4Wọ́n tafà ní ìkọ̀kọ̀ sí àwọn aláìlẹ́ṣẹ̀: 5Wọ́n, gba ara wọn níyànjú nínú èrò búburú, 6Wọ́n gbìmọ̀ àìṣòdodo, wọ́n wí pé, 7Ṣùgbọ́n Ọlọ́run yóò ta wọ́n ní ọfà; 8Ahọ́n wọn yóò sì dojú ìjà kọ wọ́n, yóò sì run wọ́n, 9Gbogbo ènìyàn yóò máa bẹ̀rù 10Jẹ́ kí olódodo kí ó yọ̀ nínú Olúwa

Napi korlát elérve

Frissítsd az előfizetésed, hogy az AI funkciókat magasabb napi korlátokkal használhasd.

Összes csomag összehasonlítása →