YOR यशायाह अध्याय 32

यशायाह 32

1Wò ó, ọba kan yóò jẹ nínú òdodo 2Ẹnìkọ̀ọ̀kan yóò jẹ́ bí ibi ìṣápamọ́ kúrò lọ́wọ́ afẹ́fẹ́ 3Nígbà náà ni ojú àwọn tí ó rí kò ní padé mọ́, 4Ọkàn àwọn oníwàdùwàdù ni yóò là tí yóò sì yè, 5A kò ní pe òmùgọ̀ ní ọlọ́lá mọ́ 6Nítorí òmùgọ̀ sọ̀rọ̀ òmùgọ̀, Olúwa kalẹ̀; 7Ibi ni gbogbo ọgbọ́n àwọn ìkà ènìyàn jẹ́, 8Ṣùgbọ́n ọlọ́lá ènìyàn a máa pète ohun ńlá 9Ẹ̀yin obìnrin tí ẹ ti gba ìtẹ́lọ́rùn gidi 10Ní ó lé díẹ̀ ní ọdún kan 11Wárìrì, ẹ̀yin obìnrin onítẹ̀lọ́rùn; 12Ẹ lu ọmú yín fún pápá ìgbádùn náà, 13àti fún ilẹ̀ àwọn ènìyàn mi, 14Ilé olódi ni a ó kọ̀sílẹ̀, 15títí a ó fi tú Ẹ̀mí sí wa lórí láti òkè wá, 16Ẹ̀tọ́ yóò máa gbé ní inú aṣálẹ̀ 17Èso òdodo náà yóò sì jẹ́ àlàáfíà; 18Àwọn ènìyàn mi yóò máa gbé ní ibùgbé àlàáfíà, 19Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé yìnyín ti tẹ́jú igbó pẹrẹsẹ 20báwo ni ẹ ó ti jẹ́ alábùkún tó,

दैनिक सीमा तक पहुंच गई

उच्च दैनिक सीमा के साथ AI सुविधाओं का उपयोग जारी रखने के लिए अपनी योजना को अपग्रेड करें।

सभी योजनाओं की तुलना करें →