YOR यशायाह अध्याय 24

यशायाह 24

1Kíyèsi i, Olúwa yóò sọ ohun 2bákan náà ni yóò sì rí 3Ilé ayé ni a ó sọ di ahoro pátápátá Olúwa ni ó ti sọ ọ̀rọ̀ yìí. 4Ilẹ̀ ayé ti gbẹ ó sì sá, 5àwọn ènìyàn ayé ti bà á jẹ́; 6Nítorí náà, ègún kan ti jẹ ayé run; 7Wáìnì tuntun ti gbẹ, àjàrà sì ti rọ, 8Àríyá ti ṣaworo ti dákẹ́ 9Kò ṣe é ṣe fún wọn láti máa mu wáìnì pẹ̀lú orin kíkọ mọ́ 10Ìlú tí a run ti dahoro, 11Ní òpópónà ni wọ́n ti ń kígbe fún wáìnì 12Ìlú ni a ti fi sílẹ̀ ní ahoro, 13Bẹ́ẹ̀ ni yóò sì rí ní orí ilẹ̀ ayé 14Wọ́n gbé ohùn wọn sókè, wọ́n sì hó fún ayọ̀; Olúwa. 15Nítorí náà ní ìlà-oòrùn ẹ fi ògo fún Olúwa; Olúwa ga, àní 16Láti òpin ayé wá ni a ti gbọ́ orin; 17Ìpayà, isà òkú, àti ìdẹ̀kùn ń dúró dè ọ́, 18Ẹnikẹ́ni tí ó bá sá nítorí ariwo ìpayà 19Ilẹ̀ ayé ti fọ́ 20Ilẹ̀ ayé yí gbiri bí ọ̀mùtí, 21Ní ọjọ́ náà ni Olúwa yóò jẹ ẹ́ ní yà 22A ó sì kó wọn jọ pọ̀, 23A ó rẹ òṣùpá sílẹ̀, ojú yóò sì ti oòrùn; Olúwa àwọn ọmọ-ogun yóò jẹ ọba

दैनिक सीमा तक पहुंच गई

उच्च दैनिक सीमा के साथ AI सुविधाओं का उपयोग जारी रखने के लिए अपनी योजना को अपग्रेड करें।

सभी योजनाओं की तुलना करें →