YOR यशायाह अध्याय 26

यशायाह 26

1Ní ọjọ́ náà ni a ó kọ orin yìí ní ilẹ̀ Juda. 2Ṣí àwọn ìlẹ̀kùn 3Ìwọ yóò pa á mọ́ ní àlàáfíà pípé 4Gbẹ́kẹ̀lé Olúwa títí láé, Olúwa, Olúwa ni àpáta ayérayé náà. 5Ó sọ àwọn tí ó ń gbé ní òkè di onírẹ̀lẹ̀ 6Ẹsẹ̀ tẹ̀ ẹ́ mọ́lẹ̀ 7Ipa ọ̀nà àwọn olódodo tẹ́jú, 8Bẹ́ẹ̀ ni, Olúwa, rírìn ní ọ̀nà òfin rẹ 9Ọkàn mi ń pòùngbẹẹ̀ rẹ ní ọ̀gànjọ́ òru; 10Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a fi oore-ọ̀fẹ́ hàn sí àwọn ìkà Olúwa sí. 11Olúwa, ti gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè 12Olúwa, ìwọ fi àlàáfíà lélẹ̀ fún wa; 13Olúwa Ọlọ́run wa, àwọn olúwa mìíràn 14Wọ́n ti kú báyìí, wọn ò sí láààyè mọ́; 15Ìwọ ti mú orílẹ̀-èdè gbòòrò, Olúwa; 16Olúwa, wọ́n wá sọ́dọ̀ rẹ nínú ìpọ́njú wọn; 17Gẹ́gẹ́ bí obìnrin tí ó lóyún tí ó sì fẹ́rẹ̀ bímọ Olúwa. 18Àwa wà nínú oyún, a wà nínú ìrora, 19Ṣùgbọ́n àwọn òkú yín yóò wà láààyè 20Ẹ lọ, ẹ̀yin ènìyàn mi, ẹ wọ ìyẹ̀wù yín lọ 21Kíyèsi i, Olúwa ń jáde bọ̀ láti ibùgbé rẹ̀

दैनिक सीमा तक पहुंच गई

उच्च दैनिक सीमा के साथ AI सुविधाओं का उपयोग जारी रखने के लिए अपनी योजना को अपग्रेड करें।

सभी योजनाओं की तुलना करें →