YOR Psaumes Chapitre 82

Psaumes 82

YOR · Comparer · Audio

1lọ́run ń ṣàkóso nínú ìpéjọpọ̀ ńlá, 2“Yóò ti pẹ́ tó tí ìwọ yóò máa gbèjà àwọn aláìṣòdodo 3Gbèjà àwọn aláìlágbára àti aláìní baba; 4Gba àwọn aláìlágbára àti aláìní; 5“Wọn kò mọ̀ ohun kankan, 6“Mo wí pé, ‘Ẹyin ní “Ọlọ́run òrìṣà”; 7Ṣùgbọ́n ẹ̀yin ó kú bí ènìyàn lásán; 8Dìde, Ọlọ́run, ṣe ìdájọ́ ayé,

Limite quotidienne atteinte

Mettez à jour votre plan pour continuer à utiliser les fonctionnalités de l'IA avec des limites quotidiennes plus élevées.

Comparer tous les forfaits →