Psaumes 67
1Kí Ọlọ́run kí ó ṣàánú fún wa kí ó sì bùkún fún wa, 2kí ọ̀nà rẹ le di mí mọ̀ ní ayé, 3Kí àwọn ènìyàn kí ó yìn ọ́, Ọlọ́run; 4Kí orílẹ̀-èdè kí ó yọ̀, kí ó sì kọrin fún ayọ̀, 5Kí àwọn ènìyàn kí ó yìn ọ́, Ọlọ́run; Sela. 6Nígbà náà ní ilẹ̀ yóò mú ìkórè rẹ̀ wá, Ọlọ́run, 7Ọlọ́run yóò bùkún fún wa,