Psaumes 104
1Yin Olúwa, ìwọ ọkàn mi. Olúwa Ọlọ́run mi, ìwọ tóbi jọjọ; 2Ìwọ fi ìmọ́lẹ̀ bo ara rẹ gẹ́gẹ́ bí aṣọ; 3ìwọ tí ó fi omi ṣe ìtì igi àjà ìyẹ̀wù rẹ. 4Ó fi ẹ̀fúùfù ṣe àwọn ìránṣẹ́ rẹ, 5O fi ayé gúnlẹ̀ lórí àwọn ìpìlẹ̀; 6Ìwọ fi ibú omi bò ó mọ́lẹ̀ bí aṣọ; 7Ṣùgbọ́n nípa ìbáwí rẹ ni àwọn omi lọ, 8wọ́n sàn kọjá lórí àwọn òkè, 9Ìwọ gbé òpin tí wọn kò lè kọjá rẹ̀ kálẹ̀; 10Ìwọ mú kí ìsun da omi sí àwọn àfonífojì; 11Wọ́n fún gbogbo àwọn ẹranko igbó ní omi 12Àwọn ẹyẹ ojú òfúrufú tẹ́ ìtẹ́ wọn lẹ́gbẹ̀ẹ́ omi 13Ó bu omi rin àwọn òkè láti ìyẹ̀wù rẹ̀ wá; 14Ó mú kí koríko hù jáde fún àwọn ẹranko láti jẹ 15Ọtí wáìnì tí ó ń mú ọkàn ènìyàn yọ̀, 16Àwọn igi Olúwa ni a bu omi rin dáradára, 17Níbẹ̀ ní àwọn ẹyẹ ṣe ìtẹ́ wọn 18Àwọn òkè gíga ni ààbò fún àwọn ewúrẹ́ igbó; 19Òṣùpá jẹ́ àmì fún àkókò 20Ìwọ mú òkùnkùn wá, ó sì di òru, 21Kìnnìún ń bú ramúramù fún ohun ọdẹ wọn 22Oòrùn ràn, wọ́n sì kó ara wọn jọ, 23Ọkùnrin jáde lọ sí iṣẹ́ wọn, 24Iṣẹ́ rẹ ti pọ̀ tó, Olúwa! 25Bẹ́ẹ̀ ni Òkun yìí tí ó tóbi, tí ó sì ni ìbú, 26Níbẹ̀ ni ọkọ̀ ń lọ síwá sẹ́yìn, 27Àwọn wọ̀nyí ń wò ọ́ 28Nígbà tí ìwọ bá fi fún wọn, 29Nígbà tí ìwọ bá pa ojú rẹ mọ́ 30Nígbà tí ìwọ rán ẹ̀mí rẹ, 31Jẹ́ kí ògo Olúwa wà pẹ́ títí láé; Olúwa kí ó dùn ní ti iṣẹ́ rẹ̀, 32ẹni tí ó wo ayé, tí ó sì wárìrì, 33Ní gbogbo ayé mi ní n ó kọrin sí Olúwa: Olúwa 34Jẹ́ kí ẹ̀kọ́ mi kí ó tẹ́ ọ lọ́rùn Olúwa. 35Ṣùgbọ́n kí ẹlẹ́ṣẹ̀ kúrò láyé Olúwa, ìwọ ọkàn mi. Olúwa.