YOR Psalm Kabanata 90

Psalm 90

YOR · Ihambing · Audio

1Olúwa, ìwọ ti jẹ́ ibùgbé wa ní gbogbo ìran dé ìran. 2Kí a tó bí àwọn òkè ńlá 3Ìwọ yí ènìyàn padà sí erùpẹ̀, 4Nítorí pé ìgbà tí ẹgbẹ̀rún (1,000) ọdún bá kọjá lójú rẹ, 5Ìwọ gbá ènìyàn dànù nínú oorun ikú; 6Lóòtítọ́, ní òwúrọ̀, ó yọ tuntun 7A pa wá run nípa ìbínú rẹ 8Ìwọ ti gbé ẹ̀ṣẹ̀ wa ka iwájú rẹ, 9Gbogbo ọjọ́ wa ń kọjá lọ lábẹ́ ìbínú rẹ; 10Àádọ́rin ọdún ni iye ọjọ́ ọdún wá, 11Ta ni ó mọ agbára ìbínú rẹ? 12Kọ́ wa bí a ti ń kaye ọjọ́ wa dáradára, 13Yípadà, Olúwa! Yóò ti pẹ́ tó? 14Tẹ́ wa lọ́rùn ní òwúrọ̀ nínú ìṣeun ìfẹ́ rẹ, 15Mú inú wa dùn bí ọjọ́ tí ìwọ ti pọ́n wa lójú, 16Jẹ́ kí a fi iṣẹ́ rẹ̀ han àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀, 17Jẹ́ kí ẹwà Olúwa Ọlọ́run wa wà lára wa;

Naabot na ang Pang-araw-araw na Limitasyon

I-upgrade ang iyong plan upang magpatuloy sa paggamit ng AI features na may mas mataas na daily limits.

Ikumpara ang lahat ng plano →