YOR Psalm Kabanata 113

Psalm 113

YOR · Ihambing · Audio

1 máa yin Olúwa. Olúwa, Olúwa. 2Fi ìbùkún fún orúkọ Olúwa láti 3Láti ìlà-oòrùn títí dé ìwọ̀ rẹ̀ Olúwa ni kí a máa yìn. 4Olúwa ga lórí gbogbo orílẹ̀-èdè, 5Ta ló dàbí Olúwa Ọlọ́run wa, 6Tí ó rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ láti wò 7Ó gbé òtòṣì dìde láti inú erùpẹ̀, 8Kí ó le mú un jókòó pẹ̀lú àwọn ọmọ-aládé 9Ó mú àgàn obìnrin gbé inú ilé, Olúwa.

Naabot na ang Pang-araw-araw na Limitasyon

I-upgrade ang iyong plan upang magpatuloy sa paggamit ng AI features na may mas mataas na daily limits.

Ikumpara ang lahat ng plano →