YOR Psalm Kabanata 56

Psalm 56

YOR · Ihambing · Audio

1àánú fún mi, Ọlọ́run, 2Àwọn ọ̀tá mi ń lé mi ní gbogbo ọjọ́, 3Nígbà tí ẹ̀rù bà ń bà mí, 4Nínú Ọlọ́run èmi yóò máa yìn ọ̀rọ̀ rẹ, 5Wọn ń yí ọ̀rọ̀ mí ní gbogbo ọjọ́, 6Wọn kó ara wọn jọ, wọ́n ba. 7San ẹ̀san iṣẹ́ búburú wọ́n fún wọn; 8Kọ ẹkún mi sílẹ̀; 9Nígbà náà ni àwọn ọ̀tá mi yóò pẹ̀yìndà 10Nínú Ọlọ́run, ẹni tí mo yìn ọ̀rọ̀ rẹ̀ Olúwa, ẹni tí mo yin ọ̀rọ̀ rẹ̀, 11nínú Ọlọ́run ni ìgbẹ́kẹ̀lé mi: 12Mo jẹ́ ẹ̀jẹ́ lábẹ́ rẹ Ọlọ́run: 13Nítorí ìwọ tí gbà mí lọ́wọ́ ikú

Naabot na ang Pang-araw-araw na Limitasyon

I-upgrade ang iyong plan upang magpatuloy sa paggamit ng AI features na may mas mataas na daily limits.

Ikumpara ang lahat ng plano →