YOR Psalm Kabanata 19

Psalm 19

YOR · Ihambing · Audio

1Àwọn ọ̀run ń sọ nípa ti ògo Ọlọ́run; 2Wọ́n ń fọhùn ní ọjọ́ dé ọjọ́; 3Kò sí ohùn tàbí èdè 4Ohùn wọn jáde lọ sí gbogbo orílẹ̀ ayé, 5Tí ó dàbí ọkọ ìyàwó tí ó ń jáde ti yàrá rẹ̀ wá, 6Ìjáde lọ rẹ̀ ni láti òpin ọ̀run wá 7Pípé ni òfin Olúwa, Olúwa dánilójú, 8Ìlànà Olúwa tọ̀nà, Olúwa ni mímọ́, 9Ìbẹ̀rù Olúwa mọ́, Olúwa dájú 10Wọn ṣọ̀wọ́n ju wúrà lọ, 11Nípa wọn ni a ti ṣí ìránṣẹ́ rẹ̀ létí; 12Ta ni ó lè mọ àṣìṣe rẹ̀? 13Wẹ ìránṣẹ́ rẹ mọ́ kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ àmọ̀ọ́n-mọ̀-dá; 14Jẹ́ kí ọ̀rọ̀ ẹnu mi àti àṣàrò ọkàn mi Olúwa àpáta mi, àti Olùdáǹdè mi.

Naabot na ang Pang-araw-araw na Limitasyon

I-upgrade ang iyong plan upang magpatuloy sa paggamit ng AI features na may mas mataas na daily limits.

Ikumpara ang lahat ng plano →